Imesi ilu mi o . Imesi ilu to Dara. Ilu olokiki, ilu gbajumo Imesi ojugbaye nko ni gbagbe re. Agbajowo sohun lafi n soya – E je ka parapo ka gbe ilu wa ga Omo imesi N’ile ati lehin odi, E ma jeka gbagbe Ile.
Imesi ilu mi o Imesi ilu to Dara Ilu olokiki ilu gbajumo Imesi ojugbaye nko ni gbagbe re.
COMPOSED BY
ADE BASCO RE-ARANGED AND SCORED BY ASAOLU VICTOR AYODELE