Imesi Ekiti Anthem

Imesi ilu mi o .
Imesi ilu to Dara.
Ilu olokiki, ilu gbajumo
Imesi ojugbaye nko ni gbagbe re.
Agbajowo sohun lafi n soya –
E je ka parapo ka gbe ilu wa ga
Omo imesi N’ile ati lehin odi, E ma jeka gbagbe Ile.

 

Imesi ilu mi o
Imesi ilu to Dara
Ilu olokiki ilu gbajumo
Imesi ojugbaye nko ni gbagbe re. 

 

TONIC SOLFA
d,-d,m- s,m,r-d
d- d,s-d f f- f r
r,f,m,f,m,r,l,d,t-l,s
s,s,d,s,s,s,s-d,t,l,s-r,d
d,-s,m,s- s,m,d,d,r,r,l
m,f,f,r,r,l- m,m,t-r,d,-d,-
m,m,d,d,s,s,d,r,m,d,r,r-
m,f,m,r,l-d,t,d,

 

COMPOSED BY
ADE BASCO RE-ARANGED AND SCORED BY ASAOLU VICTOR AYODELE