Welcome to

Imesi Ojugbaye

Kingdom

WhatsApp Image 2021 05 31 at 6.23.22 PM

Brief History

Imesi-Ekiti was founded by OJUGBAYE, one of the grandsons of Oduduwa. He was reported to have migrated from llarẹ Quarters, Ile-Ifẹ at the same time with his two brothers: – Ọlabomoju, Ọnadeji. Also, Ọlọya (leader of the Omuos) journeyed with the three brothers and their followers through, among other places, Igbajọ, Ijero and Ikọle. Ọlọya settled with his people at Omuo, the three brothers; Ojugbaye, Ọlabomoju and Ọnadeji continued their journey downwards Ọsẹ River to settle at the present site of 1. Imesi Ekiti – Ojugbaye, 2. Ode-Ekiti – Ọlabomoju and 3. Egbe – Ọnadeji. The culture, tradition, Origin, and norms of these three communities are quite similar.

icon01-free-img

Owa Agbogbomoja. Agbomoni buruku ori. Omo uku panitan a ndare un. Omo oiuda enini lako Omo oluda fere bi ojiji Omo amomo rubo tan keye re ya ka rufin ana. A o mo gbe o luami Aromo riye boni rugba Omo ekun tanni kere mu Omo Onimesi Ojugbaye okun omo a mi ranyin bi okun Omo Olusin kan mu—o—gbogboro Omo Olusin kan dodobale nki ki an si sagba umodaaji. Agba Umo ni ma kiki mi si ki sin rin. Omo olusin ko to pepe ferin Oba ijoko iponna adumila. Omo Olusin kan judi un kan si dodo Adumila Lusin lusin mi je, Udi udi mi ja. Mi yo jon dede mu pako mi lusin ran. Oseketerepe ni joko seti omi kefo ara moda oun. On ni joko sigbo Agbeke se egigun oni keere. Omo Olugbo agbe kan oyele mo ye, Oyele yeleyele ko egigun oni. Omo etun koko odo Iseku, ke ita bi eyini lori. Etun koko odo Iseku ko ti sukun edo rororo Omo oluroko gbeyesin. Omo oluroko kogungungun da funfun segbe orun kannaknna Omo oluroko isole deni. Iroko ko sole deni ke somo oni sii.

icon02-free-img

Iroko ko sole deni ke kini erubo oja Omokan bi gbeyin lulerin e de yo mayiye uroko. Iroko ojule rin da tale bo. Ai room owa ai jeji mora Obasitu pa Ako imole ija gbo dela ko kobasitu deni. Omo akoranyin mu pakiti ose gun. Ose jemi juru mo rogiri sapo. Ekutele lie ma po mije. Apadidi pe loko ale ma ke. Kohumonsin. Omo agbogbo ni anran. Omo agbagba lila raun akara. Omo a s'eyes'aba arore. Omo a yena owuro kutu bi Olodurnare. Omo uvula gori eye re lagogo ude. Omo adiye lorokun ejo Owa bu mi lokuku, osupa ni ma b'owa. Owa amokun o o (owo) a mokun ese, a maso funfun rururu egele. Ko'wumo de so, kegbodo re mo dela, Owa baba "Olusoji" maso funfun rururu. Omo a jiwajiwa ileke. A mu dudu pari ade. O mu da tere peru, o muda jinginni porno. Omo Olona eleji morin. Ona ko ba ki mi m'oya mi rin ko ya wi an mi. Usi kejabeni, emuda boni, Omo usin ke jafiyo ko e re pon. Ogbigbo ni ba lori Usin iwo isugun roro.

icon03-free-img

Esimirin ni gun lori usin ko ri ihoho ayaba lure re. Ko kan kuku seye lila ni ri ihoho ayaba se a ba paa. Uku ekeji orisa. Omo qbamigbami serum miamia. O qba mi tan moni torun mi Omo onigeru atorire ya o. Omo Onigeru a mepo pa. Omo kan bire na mu Iseku we. Iseku na mu we baba mi. Owa ko ro mi laso, ko mo romi laso oloko. Aso kan mu koko oni dogo re Iowa mu ko mi O wa ni mu oja ododo polori igbe ona oke aara. Oja ododo yun mi lora ni toni to fefe ma lo. Omo a mo mo oko tohun tobo idi re. Omo eras ni mo to mi to o (iwo) re. Orun ni oja ko mo a mo ya mi. Omo uku aba--eye. Omo olope kan moja da, kan mo ja ra kan mo gbo koro ugba eni. Oun na moja da kan ri lolo ara eni. Omo oloju ogogoro. A ma kiko udi ogagara. Omo ekun tere sa jija. O Omo sa le kan mo. A ko lona serum laa. Omo odundun ladin. Ajanaku sugbo kijikiji Ogbigbi lila sugbo rimirimi. Omo erin a ma—ka jati. Erin kan soso ona aofin.

cropped cropped EKITI

MEETINGS OF ONIMESI IN COUNCIL

  1. Meeting Calendar 2022

IMESI EKITI NEWS BOX

Wale Ojo Lanre
ONIMESI PLANTS MUSEUM

Wale Ojo Lanre OMG! See what is happening in Imesi Ekiti? As Onimesi plants Museum of Royal Antiquities Truth. you wonder why all these lofty things are now happening in Imesi Ekiti. 

Onimesi confers title on Victor Agunbiade
WhatsApp Image 2021 04 20 at 4.56.12 AM
Breaking News! Potsherd pavement discovered in Imesi Ekiti, Ekiti State

An archaeological and touristic feature, a long potsherd pavement has been unearthed at the palace of Onimesi of Imesi Ekiti, Gboyin Local Government of Ekiti State.

At Odun Ade Festival,Yoruba Obas Promised Support for Onimesi Ekiti

odun ade festival
2 Regaining the Legacy scaled e1614180145581
Governor Kayode Fayemi gives Oba Festus Olatunji Olatunde, instrument of appointment and staff of office.

The new Onimesi of Imesi Ekiti, Oba Festus Olatunji Olatunde, on Monday received his instrument of appointment and staff of office from Governor Kayode Fayemi.

download